وَكَذَٰلِكَ أَوۡحَيۡنَآ إِلَيۡكَ رُوحٗا مِّنۡ أَمۡرِنَاۚ مَا كُنتَ تَدۡرِي مَا ٱلۡكِتَٰبُ وَلَا ٱلۡإِيمَٰنُ وَلَٰكِن جَعَلۡنَٰهُ نُورٗا نَّهۡدِي بِهِۦ مَن نَّشَآءُ مِنۡ عِبَادِنَاۚ وَإِنَّكَ لَتَهۡدِيٓ إِلَىٰ صِرَٰطٖ مُّسۡتَقِيمٖ 52
Gẹgẹbbi a se ransẹ imisi si awọn anọbi siwaju - irẹ ojisẹ - ni a fi Alukuraani ransẹ si ọ lati ọdọ Wa, iwọ ko mọ siwaju rẹ awọn tira sanmọ ti a sọkalẹ fun awọn ojisẹ, bẹẹni iwọ ko mọ iru igbagbọ naa? Sugbọn a sọ Alukuraani yii kalẹ ni itansan ti a ma nfi ntọ ẹniti o ba wu wa ninu ẹru Wa sọna, ati wipe dajudaju iwọ ni o maa tọka fun awọn eniyan lọsi oju ọna ti o duro tọ, ohun si ni ẹsin alaafia.
صِرَٰطِ ٱللَّهِ ٱلَّذِي لَهُۥ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَمَا فِي ٱلۡأَرۡضِۗ أَلَآ إِلَى ٱللَّهِ تَصِيرُ ٱلۡأُمُورُ 53
Oju ọna Allah eyiti o ni ohun ti o wa ni gbogbo sanmọ ati Oun ni o si tun ni gbogbo ohun ti o wa nilẹ niti ẹda ati ọla ati idari eto, dandan ni gbogbo ọrọ nibi ipebubu rẹ ati idari rẹ ati eto rẹ yoo sẹri lọsi ọdọ Allah nikan soso.
سورة (MAKIYYAH)
Ikininilọ nibi adanwo ti nbẹ nibi yodoyindin isẹmi aye; ki o ma ba jẹ atẹgun lọsi ibi ẹbọ.
حمٓ 1
(حمٓ) (Ha Mim) ọrọ ti gbawaju lori iran iru rẹ ni ọgba ọrọ bakọrah
وَٱلۡكِتَٰبِ ٱلۡمُبِينِ 2
Allah fi Alukuraani bura eyiti o nsdalaye oju ọnaamọ lọsi ibi ododo.
إِنَّا جَعَلۡنَٰهُ قُرۡءَٰنًا عَرَبِيّٗا لَّعَلَّكُمۡ تَعۡقِلُونَ 3
Awa ni a se ni nkan kika pẹlu ede larubawa; ki ẹ le se laakaye -ẹyin awujọ ti a sọ ọ kalẹ pẹlu ahọn yin- awọn itumọ rẹ, ki ẹ si gbọ ọ ye ki ẹ le mu lati ọdọ awọn ijọ miran.
وَإِنَّهُۥ فِيٓ أُمِّ ٱلۡكِتَٰبِ لَدَيۡنَا لَعَلِيٌّ حَكِيمٌ 4
Atipe dajudaju Alukuraani wa ninu ọpọn ti a daabobo, o ni ipo giga ati agbega, o si ni ọgbọn paapaa wọn ti yẹ gbogbo awọn aayah rẹ wo finin nibi awọn asẹ Rẹ ati ohun ti O kọ.
أَفَنَضۡرِبُ عَنكُمُ ٱلذِّكۡرَ صَفۡحًا أَن كُنتُمۡ قَوۡمٗا مُّسۡرِفِينَ 5
Se a o gbe sisọ Alukuraani kalẹ le yin lori ju silẹ ni niti gigunri nitori pipọ yin lẹbọ ati awọn ẹsẹ? A ko le se eleyi bikosepe ikẹ ti o wa pẹlu yin nibukaata si ohun ti o yatọ si eleyi.
وَكَمۡ أَرۡسَلۡنَا مِن نَّبِيّٖ فِي ٱلۡأَوَّلِينَ 6
Melo anọbi ni a gbe dide ninu awọn ijọ ti o ti siwaju.
وَمَا يَأۡتِيهِم مِّن نَّبِيٍّ إِلَّا كَانُواْ بِهِۦ يَسۡتَهۡزِءُونَ 7
Anọbi kan nii wa ba awọn ijọ ti o siwaju yii lati ọdọ Allah ayaafi ki wọn fi se yẹyẹ.
فَأَهۡلَكۡنَآ أَشَدَّ مِنۡهُم بَطۡشٗا وَمَضَىٰ مَثَلُ ٱلۡأَوَّلِينَ 8
A mun iparun ba awọn ti o lagbara ju awọn ijọ naa lọ, a ko le kagara lati mu iparun ba awọn ti o lẹ si wọn, iroyin pipa awọn ijọ ti o ti re kọja lọ run si ti re kọja ninu Alukuraani gẹgẹ bi hadi ati samuud ati ijọ Luuth ati awọn ijọ madiyana.
وَلَئِن سَأَلۡتَهُم مَّنۡ خَلَقَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضَ لَيَقُولُنَّ خَلَقَهُنَّ ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡعَلِيمُ 9
Ti o ba beere - irẹ ojisẹ - lọwọ awọn ẹlẹbọ opurọ yii: taani o da gbogbo sanmọ, taani o si da ilẹ? Paapaa wọn yoo sọ esi fun ibeere rẹ: alagbara eyiti ẹnikankan ko le bori ni o da wọn, Onimimọ si gbogbo nkan.
ٱلَّذِي جَعَلَ لَكُمُ ٱلۡأَرۡضَ مَهۡدٗا وَجَعَلَ لَكُمۡ فِيهَا سُبُلٗا لَّعَلَّكُمۡ تَهۡتَدُونَ 10
Allah ti o tẹ ilẹ fun yin, O si se ni nkan ti ẹ o ma tẹ pẹlu gigisẹ yin, O si se awọn ọna ninu oke ati awọn ọgbun fun yin nibẹ; ni ireti ki ẹ le ti ibẹ mọna nibi irin yin.
Wọn pe imisi ni ẹmin nitori pataki imisi nibi imọna ọmọniyan, o wa ni ipo ẹmin si ara.
Imọna si a fi ti si ọdọ ojisẹ naa ti ikẹ ati ọla nbẹ fun ni imọna itọnisọna kii se imọna kongẹ.
Igbagbọ mimu Ọlọhun nikan ni olutọju ti o wa ni ọdọ ẹlẹbọ ko le se wọn ni anfaani ni ọjọ igbende.