وَلَمَّا تَوَجَّهَ تِلۡقَآءَ مَدۡيَنَ قَالَ عَسَىٰ رَبِّيٓ أَن يَهۡدِيَنِي سَوَآءَ ٱلسَّبِيلِ 22
Nigbati o nlọ ti o da oju kọ ọna madiyana, o sọ wipe: o seese ki Ọlọhun Ọba mi tọ mi si oju ọna rere ti nko si ni sọnu kuro nibẹ.
وَلَمَّا وَرَدَ مَآءَ مَدۡيَنَ وَجَدَ عَلَيۡهِ أُمَّةٗ مِّنَ ٱلنَّاسِ يَسۡقُونَ وَوَجَدَ مِن دُونِهِمُ ٱمۡرَأَتَيۡنِ تَذُودَانِۖ قَالَ مَا خَطۡبُكُمَاۖ قَالَتَا لَا نَسۡقِي حَتَّىٰ يُصۡدِرَ ٱلرِّعَآءُۖ وَأَبُونَا شَيۡخٞ كَبِيرٞ 23
Nigbati o de ibi omin madiyana eyiti wọn mu omin nibẹ, o ri awọn ijọ kan ninu awọn eniyan ti wọn nfun awọn ẹranko wọn ni omin, o si tun ri yatọ si wọn awọn obirin meji kan ti wọn so aguntan wọn mọlẹ kuro nibi omin ki awọn eniyan le mumi, Musa ẹniti ọla nbẹ fun waa sọ fun awọn mejeeji: kinni o nse ẹyin mejeeji ti ẹ ko le mu onin pẹlu awọn eniyan? Awọn mejeeji wa sọ fun pe: isesi wa ni ki a ta kete, a ko nii mumi titi ti awọn daran daran yoo fi pa ẹyin da; lati sọra fun riro pọ mọ wọn, bẹẹni baba wa si ti dagba lọjọ ori, ko lagbara lati wa mumin, o wa di dandan fun lati wa fun awọn aguntan wa ni omin.
فَسَقَىٰ لَهُمَا ثُمَّ تَوَلَّىٰٓ إِلَى ٱلظِّلِّ فَقَالَ رَبِّ إِنِّي لِمَآ أَنزَلۡتَ إِلَيَّ مِنۡ خَيۡرٖ فَقِيرٞ 24
O kẹ awọn mejeeji, o si ba wọn fun awọn aguntan wọn ni omin, lẹyin naa, o wa pẹyin da lọsi abẹ iboji, o si sin mi sibẹ, o wa pe Ọlọhun Ọba rẹ ni ẹniti o nsẹri bukaata rẹ si I, o wa sọpe: Ọlọhun mi, dajudaju emi, kilode ti O fi sọ oore ti yoo tun ma ngbẹngbẹ kalẹ fun mi.
فَجَآءَتۡهُ إِحۡدَىٰهُمَا تَمۡشِي عَلَى ٱسۡتِحۡيَآءٖ قَالَتۡ إِنَّ أَبِي يَدۡعُوكَ لِيَجۡزِيَكَ أَجۡرَ مَا سَقَيۡتَ لَنَاۚ فَلَمَّا جَآءَهُۥ وَقَصَّ عَلَيۡهِ ٱلۡقَصَصَ قَالَ لَا تَخَفۡۖ نَجَوۡتَ مِنَ ٱلۡقَوۡمِ ٱلظَّٰلِمِينَ 25
Nigbati awọn mejeeji lọ, wọn fun baba wọn ni iro rẹ, o si ran ọkan ninu wọn si i pe ki o pe e wa, bẹẹni o wa ni ẹniti o nrin pẹlu itiju, o sọpe dajudaju baba mi npe ọ ki o wa ba a, ni erongba ki o le san ọ lẹsan owo ọya rẹ lori bibawa fun ẹran lomin, nigbati Musa lọ ba baba wọn, ti o si fun niro awọn iroyin rẹ, o sọ ọ fun ni ẹniti o nfi i lọkan balẹ: mase paya, o ti la kuro ninu ijọ alabosi tii se fir'aona ati awọn ijọ rẹ, tirope dajudaju wọn ko nikapa lori ilẹ madiyana, suta wọn ko le de ọdọ rẹ.
قَالَتۡ إِحۡدَىٰهُمَا يَٰٓأَبَتِ ٱسۡتَٔۡجِرۡهُۖ إِنَّ خَيۡرَ مَنِ ٱسۡتَٔۡجَرۡتَ ٱلۡقَوِيُّ ٱلۡأَمِينُ 26
Ọkan ninu awọn ọmọ birin rẹ meji naa sọpe: irẹ baba mi, gba a ni osisẹ ki o le maa da awọn agutan wa, o lẹtọ ki o gba a; nitori agbara ati ifọkantan ti o papọ si lọdọ, agbara ni yoo fi maa se ounti o ba gbe fun un nisẹ, bẹẹni ifọkantan ni yoo fi maa daabobo ounti o ba gbe si lọdọ.
قَالَ إِنِّيٓ أُرِيدُ أَنۡ أُنكِحَكَ إِحۡدَى ٱبۡنَتَيَّ هَٰتَيۡنِ عَلَىٰٓ أَن تَأۡجُرَنِي ثَمَٰنِيَ حِجَجٖۖ فَإِنۡ أَتۡمَمۡتَ عَشۡرٗا فَمِنۡ عِندِكَۖ وَمَآ أُرِيدُ أَنۡ أَشُقَّ عَلَيۡكَۚ سَتَجِدُنِيٓ إِن شَآءَ ٱللَّهُ مِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ 27
Baba wọn sọ ni ẹniti o nba Musa ẹniti ọla nbẹ fun sọrọ: dajudaju mo gbero lati fi ọkan ninu awọn ọmọbirin yii fun ọ lori ki owo ori rẹ jẹ dida agutan wa fun ọdun mẹjọ, ti o ba jẹ ki ọdun naa pe mẹta, eleyi jẹ ọla lati ọdọ rẹ kii se dandan fun ọ, iwọ yoo ri mi - ti Allah ba fẹ - ninu ẹniire ẹniti yoo pe adehun, ti ko si ni ja adehun.
قَالَ ذَٰلِكَ بَيۡنِي وَبَيۡنَكَۖ أَيَّمَا ٱلۡأَجَلَيۡنِ قَضَيۡتُ فَلَا عُدۡوَٰنَ عَلَيَّۖ وَٱللَّهُ عَلَىٰ مَا نَقُولُ وَكِيلٞ 28
Musa ẹniti ọla nbẹ fun sọpe: eleyi ni ohun ti o wa laarin emi ti iwọ lori ohun ti a ta koko le lori, eyikeyi ninu igba mejeeji ti mo ba fi sisẹ fun ọ: ọdun mẹjọ tabi ọdun mẹwa, maa di ẹniti o ti pe ohun ti o wa lọrun mi, mase beere fun alekun lọdọ mi, Ọlọhun Allah to ni olusọ ohun ti a ta koko le lori, alamojuto rẹ.
Sisẹri lọ si ọdọ Allah jẹ ọna ọla ni aye ati lọrun.
Ituju ọmọbirin ti o jẹ musulumi jẹ okunfa apọnle ati giga ipo rẹ.
Fifi obirin kun wọ nibi erongba ati gbigbe ara le erongba ti o ba se deedee alamọri ti o dara.
Agbara ati ifọkantan jẹ iroyin meji ti o wulo fun isaseyọri.
Titọ ki owo ori jẹ anfaani.