إِذَا رَأَتۡهُم مِّن مَّكَانِۢ بَعِيدٖ سَمِعُواْ لَهَا تَغَيُّظٗا وَزَفِيرٗا 12
Nigbati ina ba fi oju kan awọn keferi ni asiko ti wọn da wọn lọsi inu rẹ lati aaye ti jinna, wọn yoo maa gbọ lilekoko iho rẹ ati ahun ijaya lati ibi lilikoko ibinu rẹ le wọn lori.
وَإِذَآ أُلۡقُواْ مِنۡهَا مَكَانٗا ضَيِّقٗا مُّقَرَّنِينَ دَعَوۡاْ هُنَالِكَ ثُبُورٗا 13
Ti wọn ba ju awọn keferi wọnyi si inu ina jahanamọ ni aaye ti o fun ninu rẹ, ti wọn sun ọwọ wọn mọ ibi ọrun wọn pẹlu sẹkẹsẹkẹ, wọn yoo maa sepe ikparun le ara wọn; ni irankan bibọ kuro nibẹ.
لَّا تَدۡعُواْ ٱلۡيَوۡمَ ثُبُورٗا وَٰحِدٗا وَٱدۡعُواْ ثُبُورٗا كَثِيرٗا 14
Ẹ mase sepe iparun ẹyọkan loni -ẹyin keferi- ẹ sepe iparun ti o pọ, sugbọn wọn koo jẹpe yin lọ si ibi ohun ti ẹ nfẹ bikosepe ẹyin yoo sẹku ninu iya inira gbere ni.
قُلۡ أَذَٰلِكَ خَيۡرٌ أَمۡ جَنَّةُ ٱلۡخُلۡدِ ٱلَّتِي وُعِدَ ٱلۡمُتَّقُونَۚ كَانَتۡ لَهُمۡ جَزَآءٗ وَمَصِيرٗا 15
Sọ fun wọn - irẹ ojisẹ -: se iya ti a sọ yii, ti wọn royin fun yin ni o loore ni tabi ọgba idẹra lailai eyiti idẹkun rẹ yoo maa lọ, ti ko si nii ja lailai? Eleyi ni Allah se adehun rẹ fun awọn olupaya ninu awọn ẹru Rẹ olugbagbọ ododo, ki o le jẹ ẹsan fun wọn ati ibusẹrisi ti wọn yoo sẹri si ni ọjọ igbende.
لَّهُمۡ فِيهَا مَا يَشَآءُونَ خَٰلِدِينَۚ كَانَ عَلَىٰ رَبِّكَ وَعۡدٗا مَّسُۡٔولٗا 16
Ohun ti wọn nfẹ ninu idẹkun nbẹ fun wọn ninu ọgba idẹra naa, eleyi jẹ adehun ni ọrun Allah, ti awọn ẹru Rẹ olupaya yoo beere lọwọ Rẹ, bẹẹni adehun Allah jẹ ohun ti yoo sẹlẹ, Oun kii si yapa adehun.
وَيَوۡمَ يَحۡشُرُهُمۡ وَمَا يَعۡبُدُونَ مِن دُونِ ٱللَّهِ فَيَقُولُ ءَأَنتُمۡ أَضۡلَلۡتُمۡ عِبَادِي هَٰٓؤُلَآءِ أَمۡ هُمۡ ضَلُّواْ ٱلسَّبِيلَ 17
Ọjọ ti Allah yoo ko awọn ẹlẹbọ opurọ nni jọ, ti yoo si tun ko ohun ti wọn nsin yatọ si Allah naa jọ, yoo maa wa sọ fun awọn ohun ti wọn nsin lati fi han awọn ti wọn nsin wọn leti: se ẹyin wọnyi ni ẹ kọ awọn ẹru Mi nu lati ibi asẹ yin fun wọn ki wọn maa sin yin tabi awọn ni wọn sọnu fun ara wọn?!
قَالُواْ سُبۡحَٰنَكَ مَا كَانَ يَنۢبَغِي لَنَآ أَن نَّتَّخِذَ مِن دُونِكَ مِنۡ أَوۡلِيَآءَ وَلَٰكِن مَّتَّعۡتَهُمۡ وَءَابَآءَهُمۡ حَتَّىٰ نَسُواْ ٱلذِّكۡرَ وَكَانُواْ قَوۡمَۢا بُورٗا 18
Awọn ti wọn nsin yoo sọpe: Ọlọhun Ọba wa mọ kanga ju ki O ni akẹgbẹ lọ, ko tọ fun wa ki a mu ohun ti o yatọ si ni alaayo ti a o maa fi ara ti si lọdọ, bawo ni a o se maa pe awọn ẹru Rẹ ki wọn maa sin wa yatọ si Ọ?! Sugbọn Mo mu idẹkun ba awọn ẹlẹbọ wọnyii ninu awọn adun aye, mo si tun mu idẹkun ba awọn baba wọn siwaju wọn niti idẹnilẹkẹ titi ti wọn fi gbagbe iranti Rẹ, ti wọn si nsin nkan miran ti o yatọ si Ọ pẹlu Rẹ, wọn jẹ ijọ iparun lati ibi orribu wọn.
فَقَدۡ كَذَّبُوكُم بِمَا تَقُولُونَ فَمَا تَسۡتَطِيعُونَ صَرۡفٗا وَلَا نَصۡرٗاۚ وَمَن يَظۡلِم مِّنكُمۡ نُذِقۡهُ عَذَابٗا كَبِيرٗا 19
Paapa ẹ ti parẹ - ẹyin ẹlẹbọ - mọ awọn ti ẹ nsin yatọ si Allah nibi ohun ti ẹ npe apemọra rẹ fun wọn, ẹ ko nikapa mimu iya kuro fun ara yin tabi mimu aranse ba a nitori ikagara yin, ẹniti o ba se abosi ninu yin - ẹyin olugbagbọ ododo - pẹlu sise ẹbọ si Allah, A o fi iya ti o to bi tọ wo, iru eyi ti a fi tọ ẹniti wọn sọ wo lẹnu.
Nigbati awọn ẹlẹbọ tako jijẹun ojisẹ (ti ikẹ ati ọla nbẹ fun) ati ririn ninu awọn ọja, o fi gbolohun Rẹ da ọrọ pada si wọn lẹnu:
وَمَآ أَرۡسَلۡنَا قَبۡلَكَ مِنَ ٱلۡمُرۡسَلِينَ إِلَّآ إِنَّهُمۡ لَيَأۡكُلُونَ ٱلطَّعَامَ وَيَمۡشُونَ فِي ٱلۡأَسۡوَاقِۗ وَجَعَلۡنَا بَعۡضَكُمۡ لِبَعۡضٖ فِتۡنَةً أَتَصۡبِرُونَۗ وَكَانَ رَبُّكَ بَصِيرٗا 20
A ko gbe dide siwaju rẹ - ire ojise - ninu awọn ojisẹ ayaafi abara eniyan, wọn jẹ ẹniti o ma njẹun, wọn si ma nrin ninu awọn ọja, iwọ kii se ibẹrẹ ninu awọn ojisẹ nibi eleyi, a si apakan yin ni idanwo fun apakan - ẹyin eniyan - nibi ọrọ ati osi ati alaafia ati aisan nitori iyapa yii, se ẹ o se suuru lori ohun ti a fi dan yin wo yii, ki Allah le san yin lẹsan lori suuru yin?! Ọlọhun rẹ jẹ oluri ẹniti O se suuru ati ẹniti ko le se suuru ati ẹniti o ntẹẹle E ati ẹniti o nyapa Rẹ.
Siso asopọ laarin idẹrubani ninu iya Allah ati iseni loju kokoro si ẹsan Rẹ.
Igbadun aye muni gbagbe iranti Allah.
Jijẹ abara awọn ojisẹ jẹ idẹkun lati ọdọ Allah fun awọn eniyan ki ibasepọ wọn le rọrun.
Jijuralọ awọn eniyan nibi idẹkun ati ijiya jẹ idanwo Ọlọhun Ọba fun awọn ẹru Rẹ.